back

Oggun ñongo

ogunde baba osemi ariwo ogunde
A:baba semi ariwo
-->
mayo olona arere alaberekuo
oggun mayo olona arere alaberekuo olorisa

ogun lo de o, ogun lo de
made lo wo ni tani solo yu
ni farawa
-->
A: tani solo yu
ni farawa

oggun teri akpa tikwa ti (x2)
arere kwami lo nadi oggun (x2)
awo yo kwami la tori yesa
kwekwe oggun teri akpa tikwa ti
-->
A: arere kwami lo nadi oggun
oggun teri akpa tikwa ti
--> oggun soro ayina soro (x2)
baba elegba olukun abanya
arere soro
-->
A: baba elegba olukun abanya
ayina soro
-->
ºogun elese aribo, ogun elese aribo (x2)
baba elegba oya o, ogun elese aribo
-->
A:baba elegba oya o
ogun elese aribo
-->
A: aribo ese erio, aribo
oggun latopa era
-->
wami la ogun, wami la o
-->
wami la ogun, alawede

banla o, oggun banla o
banla o baba loni, banla ogun lode
-->
ogun wade banbara ni soro, ogun wade
ogun wade banbara ni soro, ogun wade
-->
ogun baralala okuo, ogun baralala atoleyo -->
A:atole
ºatole yo
-->
laye o, ogun arere yo sara bayile
A: arere yo sara bayile, arere yo sara bayile
-->
^bonbo laye irele leyo, me taya mando
bonbo laye
A: metekun ladyana pa' que me llama
-->
laye laye, arawo uko soyile uko, laye laye
A: arawo uko soyile uko
-->
wara wara sokende
A: sokende, sokende
A: alagwede, sokende
A: sokende, sokende oko

[sokemado]

sokemado du mare, sokemado
sokemado du mare, sokemado du mare
dipu dipu dide o, baba sokunda
sokunda alaroye sokemado du mare
-->
de verdad verdad
de verdad verdad oggun arere
yo vive en la savana alawede
-->
A: yo vive en savana
alawede
-->
akuko uko, kwele un oda
keye keye alado un mai mai

agwanile o ogun maribo, agwanile o ogun maribo
ogun a formode
orikyambele maribo
ogunde banba
A: alawede!..
A: arere..!!
A: sosolo! agwanile o arere maribo, agwanile o arere maribo
A: ogun a formode
A: oniliyabere maribo
A: ogunde banba

Awanile,
awanile koma seyidawo, awanile
A: agwanile koma seyidawo
A: kobun kobun, loma seyidawo
A: fina malu koma seyidawo
A: alagwede koma seyidawo
A: oro arere..
A: ogun maribo..

e aribo yan yan
A: arere, arere o

A: ^koko motansele yo
koko
-->
A: ogun arere awa meta
koko motansele
A: alagbwede awa meta

e iye kwa, e iye kwa
keye keye motanse
ogun alado lorisa

aribo motanse kere kete
A: motanse ogun
A: aribo motanse ogun

A:awa nile wa nile,
^awa nile mai mai
-->
A:wayo wayo kilonche
awa nile mai mai
A:wayo orisa kilonche

e afere yo
--->
amala ogun arere, amala eya
A: alagwede! amala ogun arere, amala eya
--->
e afere yo

wara wara wara wara anyo
ogun laropa wara wara
A: wara wara anyo, ogun laropa

Ata o e
-->
A:ata o, ata o nile
Benbe ata o

o nile o nile, o nile o nile,
o nile o nile, o nile o nile,

ode maro e

ode maro kuya yanyala
Awa milodo
A: e, e, e,
A: alawegde maro kuya yangala

A: (rezo) aylala oke oke beru beru(x2)
egunde un odo wima
mi seke o, wami odalade
arere seke ira

ah wami odalade
A:arere seke ira
A:baba arere seke ira
A:arere va seke ira
A:onile va seke ira
A:alagwede seke ira
A:chiridiki seke ira
A:susu lona seke ira
A:ina malu seke ira

Eya, awa wona
A: oke mayitawo

*banba loya
A: arere biyo ta loya

benbe ito
A: awe ama

*soriya okuo, soriya ogun wade
A: soriya ogun wade, soriya ogun wade,
-->
ºyo me llamo abukenke
A: soriya me llamo yo
A: alawede me llamo yo
A: baba arere me llamo yo

ogun alawegde, ile mokuwo
ogun alawegde, ile mokuwo
A: arere alawegde, ile mokuwo
A: arere alawegde, ile mokuwo

Mayilewo
A: kinindya tao

rezo
onile lode
'lansa ire' y 'iki di anda'
oggun songs
iyesa
nongo

back